Ìsíkíẹ́lì 34:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 “‘“Èmi yóò fún wọn ní oko tó lókìkí,* ìyàn ò ní pa wọ́n mọ́ ní ilẹ̀ náà,+ àwọn orílẹ̀-èdè ò sì ní fi wọ́n ṣẹlẹ́yà mọ́.+
29 “‘“Èmi yóò fún wọn ní oko tó lókìkí,* ìyàn ò ní pa wọ́n mọ́ ní ilẹ̀ náà,+ àwọn orílẹ̀-èdè ò sì ní fi wọ́n ṣẹlẹ́yà mọ́.+