Jeremáyà 3:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Ní àkókò yẹn, ilé Júdà àti ilé Ísírẹ́lì yóò rìn pa pọ̀,+ wọ́n á sì jọ wá láti ilẹ̀ àríwá sí ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá yín láti jogún.+ Hósíà 1:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 A ó sì mú kí àwọn èèyàn Júdà àti ti Ísírẹ́lì ṣọ̀kan,+ wọ́n á yan olórí fún ara wọn, wọ́n á sì jáde kúrò ní ilẹ̀ náà, nítorí ọjọ́ ńlá ni ọjọ́ náà máa jẹ́ ní Jésírẹ́lì.+
18 “Ní àkókò yẹn, ilé Júdà àti ilé Ísírẹ́lì yóò rìn pa pọ̀,+ wọ́n á sì jọ wá láti ilẹ̀ àríwá sí ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá yín láti jogún.+
11 A ó sì mú kí àwọn èèyàn Júdà àti ti Ísírẹ́lì ṣọ̀kan,+ wọ́n á yan olórí fún ara wọn, wọ́n á sì jáde kúrò ní ilẹ̀ náà, nítorí ọjọ́ ńlá ni ọjọ́ náà máa jẹ́ ní Jésírẹ́lì.+