Ìsíkíẹ́lì 34:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Èmi Jèhófà yóò di Ọlọ́run wọn,+ Dáfídì ìránṣẹ́ mi yóò sì di ìjòyè láàárín wọn.+ Èmi Jèhófà ti sọ̀rọ̀. Lúùkù 1:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹni yìí máa jẹ́ ẹni ńlá,+ wọ́n á máa pè é ní Ọmọ Ẹni Gíga Jù Lọ,+ Jèhófà* Ọlọ́run sì máa fún un ní ìtẹ́ Dáfídì bàbá rẹ̀,+
24 Èmi Jèhófà yóò di Ọlọ́run wọn,+ Dáfídì ìránṣẹ́ mi yóò sì di ìjòyè láàárín wọn.+ Èmi Jèhófà ti sọ̀rọ̀.
32 Ẹni yìí máa jẹ́ ẹni ńlá,+ wọ́n á máa pè é ní Ọmọ Ẹni Gíga Jù Lọ,+ Jèhófà* Ọlọ́run sì máa fún un ní ìtẹ́ Dáfídì bàbá rẹ̀,+