Ìsíkíẹ́lì 38:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 O máa wá láti àyè rẹ, láti ibi tó jìnnà jù ní àríwá,+ ìwọ àti ọ̀pọ̀ èèyàn pẹ̀lú rẹ, tí gbogbo wọn gun ẹṣin, ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èèyàn, àwọn ọmọ ogun tó pọ̀ gan-an.+
15 O máa wá láti àyè rẹ, láti ibi tó jìnnà jù ní àríwá,+ ìwọ àti ọ̀pọ̀ èèyàn pẹ̀lú rẹ, tí gbogbo wọn gun ẹṣin, ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èèyàn, àwọn ọmọ ogun tó pọ̀ gan-an.+