Ìsíkíẹ́lì 39:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Èmi yóò mú kí o yíjú pa dà, màá darí rẹ, màá sì mú kí o wá láti ibi tó jìnnà jù ní àríwá,+ èmi yóò sì mú ọ wá sórí àwọn òkè Ísírẹ́lì.
2 Èmi yóò mú kí o yíjú pa dà, màá darí rẹ, màá sì mú kí o wá láti ibi tó jìnnà jù ní àríwá,+ èmi yóò sì mú ọ wá sórí àwọn òkè Ísírẹ́lì.