Jóẹ́lì 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jèhófà yóò sì fi ohùn rara sọ̀rọ̀ láti Síónì,Yóò gbé ohùn rẹ̀ sókè láti Jerúsálẹ́mù. Ọ̀run àti ayé yóò sì mì jìgìjìgì;Àmọ́ Jèhófà yóò jẹ́ ibi ààbò fún àwọn èèyàn rẹ̀,+Odi ààbò fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Náhúmù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo,+ ó sì ń gbẹ̀san;Jèhófà ń gbẹ̀san, ó sì ṣe tán láti bínú.+ Jèhófà ń gbẹ̀san lára àwọn elénìní rẹ̀,Ó sì ń to ìbínú rẹ̀ jọ de àwọn ọ̀tá rẹ̀. Sekaráyà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, lẹ́yìn tí a ti yìn ín lógo, ó rán mi sí àwọn orílẹ̀-èdè tó ń kó ẹrù yín,+ pé; ‘Ẹni tó bá fọwọ́ kàn yín ń fọwọ́ kan ẹyinjú* mi.+
16 Jèhófà yóò sì fi ohùn rara sọ̀rọ̀ láti Síónì,Yóò gbé ohùn rẹ̀ sókè láti Jerúsálẹ́mù. Ọ̀run àti ayé yóò sì mì jìgìjìgì;Àmọ́ Jèhófà yóò jẹ́ ibi ààbò fún àwọn èèyàn rẹ̀,+Odi ààbò fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.
2 Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo,+ ó sì ń gbẹ̀san;Jèhófà ń gbẹ̀san, ó sì ṣe tán láti bínú.+ Jèhófà ń gbẹ̀san lára àwọn elénìní rẹ̀,Ó sì ń to ìbínú rẹ̀ jọ de àwọn ọ̀tá rẹ̀.
8 Torí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, lẹ́yìn tí a ti yìn ín lógo, ó rán mi sí àwọn orílẹ̀-èdè tó ń kó ẹrù yín,+ pé; ‘Ẹni tó bá fọwọ́ kàn yín ń fọwọ́ kan ẹyinjú* mi.+