Ìsíkíẹ́lì 43:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Ní tìrẹ, ọmọ èèyàn, ṣàlàyé bí tẹ́ńpìlì náà ṣe rí fún ilé Ísírẹ́lì,+ kí ojú lè tì wọ́n torí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,+ kí wọ́n sì ṣàyẹ̀wò àwòrán ìkọ́lé rẹ̀.*
10 “Ní tìrẹ, ọmọ èèyàn, ṣàlàyé bí tẹ́ńpìlì náà ṣe rí fún ilé Ísírẹ́lì,+ kí ojú lè tì wọ́n torí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,+ kí wọ́n sì ṣàyẹ̀wò àwòrán ìkọ́lé rẹ̀.*