Ìsíkíẹ́lì 40:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọkùnrin náà sọ fún mi pé: “Ọmọ èèyàn, la ojú rẹ sílẹ̀ dáadáa, tẹ́tí bẹ̀lẹ̀jẹ́, kí o sì fiyè sí* gbogbo ohun tí mo bá fi hàn ọ́, torí ìdí tí mo ṣe mú ọ wá síbí nìyẹn. Gbogbo ohun tí o bá rí ni kí o sọ fún ilé Ísírẹ́lì.”+
4 Ọkùnrin náà sọ fún mi pé: “Ọmọ èèyàn, la ojú rẹ sílẹ̀ dáadáa, tẹ́tí bẹ̀lẹ̀jẹ́, kí o sì fiyè sí* gbogbo ohun tí mo bá fi hàn ọ́, torí ìdí tí mo ṣe mú ọ wá síbí nìyẹn. Gbogbo ohun tí o bá rí ni kí o sọ fún ilé Ísírẹ́lì.”+