-
Ìsíkíẹ́lì 40:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Nígbà tó mú mi wá sí àgbàlá inú láti ìlà oòrùn, ó wọn ẹnubodè náà, ó sì dọ́gba pẹ̀lú àwọn yòókù.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 40:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Ibi àbáwọlé* rẹ̀ dojú kọ àgbàlá ìta, àwòrán igi ọ̀pẹ sì wà lára àwọn òpó ẹ̀gbẹ́ rẹ̀, àtẹ̀gùn mẹ́jọ ló sì dé ibẹ̀.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 40:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Ó wá mú mi wá sínú ẹnubodè àríwá,+ ó sì wọ̀n ọ́n; ó dọ́gba pẹ̀lú àwọn yòókù.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 40:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Àwọn òpó ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ kọjú sí àgbàlá ìta, àwòrán igi ọ̀pẹ wà lára àwọn òpó ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ méjèèjì, àtẹ̀gùn mẹ́jọ ló sì dé ibẹ̀.
-