-
Ìsíkíẹ́lì 42:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àwọn yàrá ìjẹun tún wà lẹ́gbẹ̀ẹ́* ògiri olókùúta tó wà ní àgbàlá ní apá ìlà oòrùn, nítòsí àyè fífẹ̀ àti ilé náà.+ 11 Ọ̀nà kan gba iwájú wọn bíi ti àwọn yàrá ìjẹun tó wà ní àríwá.+ Wọ́n gùn bákan náà, wọ́n sì fẹ̀ bákan náà, ọ̀nà tí wọ́n ń gbà jáde níbẹ̀ àti bí wọ́n ṣe kọ́ ọ rí bákan náà. Ẹnu ọ̀nà wọn
-