Ìsíkíẹ́lì 42:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọ̀nà kan gba iwájú àwọn yàrá ìjẹun* náà+ tí fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá tí gígùn rẹ̀ sì jẹ́ ọgọ́rùn-ún (100) ìgbọ̀nwọ́,* ẹnu ọ̀nà àwọn yàrá náà sì dojú kọ àríwá.
4 Ọ̀nà kan gba iwájú àwọn yàrá ìjẹun* náà+ tí fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá tí gígùn rẹ̀ sì jẹ́ ọgọ́rùn-ún (100) ìgbọ̀nwọ́,* ẹnu ọ̀nà àwọn yàrá náà sì dojú kọ àríwá.