-
Ìsíkíẹ́lì 1:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Jèhófà bá Ìsíkíẹ́lì* ọmọ àlùfáà Búúsì sọ̀rọ̀ lẹ́bàá odò Kébárì ní ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà.+ Ọwọ́ Jèhófà sì wá sórí rẹ̀ níbẹ̀.+
4 Bí mo ṣe ń wò, mo rí i tí ìjì líle+ ń fẹ́ bọ̀ láti àríwá, ìkùukùu* ńlá wà níbẹ̀, iná* sì ń kọ mànà, ìmọ́lẹ̀ tó mọ́lẹ̀ yòò+ yí i ká, ohun kan sì wà nínú iná náà tó ń tàn yanran bí àyọ́pọ̀ wúrà àti fàdákà.+
-