-
Ìsíkíẹ́lì 10:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Bí mo ṣe ń wò, àwọn kérúbù náà wá na ìyẹ́ apá wọn, wọ́n sì gbéra nílẹ̀. Àwọn àgbá kẹ̀kẹ́ náà wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ wọn nígbà tí wọ́n gbéra. Wọ́n dúró ní ẹnubodè ìlà oòrùn ní ilé Jèhófà, ògo Ọlọ́run Ísírẹ́lì sì wà lórí wọn.+
-