Ìsíkíẹ́lì 43:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mo rí ògo Ọlọ́run Ísírẹ́lì níbẹ̀ tó ń bọ̀ láti ìlà oòrùn,+ ohùn rẹ̀ sì dà bí ìró omi tó ń rọ́ jáde;+ ògo rẹ̀ sì tan ìmọ́lẹ̀ sí ayé.+
2 Mo rí ògo Ọlọ́run Ísírẹ́lì níbẹ̀ tó ń bọ̀ láti ìlà oòrùn,+ ohùn rẹ̀ sì dà bí ìró omi tó ń rọ́ jáde;+ ògo rẹ̀ sì tan ìmọ́lẹ̀ sí ayé.+