Ẹ́kísódù 40:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ìkùukùu* sì bẹ̀rẹ̀ sí í bo àgọ́ ìpàdé, ògo Jèhófà sì kún inú àgọ́ ìjọsìn náà.+ 1 Àwọn Ọba 8:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nígbà tí àwọn àlùfáà jáde láti ibi mímọ́, ìkùukùu+ kún ilé Jèhófà.+ Ìsíkíẹ́lì 44:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Lẹ́yìn náà, ó mú mi gba ẹnubodè àríwá wá sí iwájú tẹ́ńpìlì náà. Nígbà tí mo wò, mo rí i pé ògo Jèhófà kún inú tẹ́ńpìlì Jèhófà.+ Torí náà, mo dojú bolẹ̀.+
4 Lẹ́yìn náà, ó mú mi gba ẹnubodè àríwá wá sí iwájú tẹ́ńpìlì náà. Nígbà tí mo wò, mo rí i pé ògo Jèhófà kún inú tẹ́ńpìlì Jèhófà.+ Torí náà, mo dojú bolẹ̀.+