ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 22:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Sọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé kí wọ́n kíyè sára pẹ̀lú bí wọ́n á ṣe máa ṣe* ohun mímọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n má sì fi àwọn ohun tí wọ́n ń yà sí mímọ́ fún mi+ sọ orúkọ mímọ́+ mi di aláìmọ́. Èmi ni Jèhófà.

  • Nọ́ńbà 18:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Kí o tún mú àwọn arákùnrin rẹ tí wọ́n jẹ́ ara ẹ̀yà Léfì sún mọ́ tòsí, ẹ̀yà baba ńlá rẹ, kí wọ́n lè dara pọ̀ mọ́ ọ, kí wọn sì máa bá ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ ṣiṣẹ́+ níwájú àgọ́ Ẹ̀rí.+ 3 Kí wọ́n máa ṣe ojúṣe wọn fún ọ àti fún àgọ́ náà lódindi.+ Àmọ́, wọn ò gbọ́dọ̀ sún mọ́ àwọn ohun èlò ibi mímọ́ àti pẹpẹ kí ẹ̀yin tàbí àwọn má bàa kú.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́