-
Àìsáyà 9:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Àwọn tó ń darí àwọn èèyàn yìí ń mú kí wọ́n rìn gbéregbère,
Nǹkan sì ti dà rú mọ́ àwọn tó ń tẹ̀ lé wọn lójú.