Léfítíkù 17:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Kí àlùfáà wọ́n ẹ̀jẹ̀ ẹran náà sórí pẹpẹ Jèhófà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, kó sì mú kí ọ̀rá ẹran náà rú èéfín sí Jèhófà láti mú òórùn dídùn* jáde.+
6 Kí àlùfáà wọ́n ẹ̀jẹ̀ ẹran náà sórí pẹpẹ Jèhófà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, kó sì mú kí ọ̀rá ẹran náà rú èéfín sí Jèhófà láti mú òórùn dídùn* jáde.+