Ìsíkíẹ́lì 48:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Ibi tó ṣẹ́ kù jẹ́ ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) ìgbọ̀nwọ́ ní fífẹ̀, lẹ́bàá ààlà tó jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́. Ó máa jẹ́ ti gbogbo ìlú,+ wọ́n á máa gbé ibẹ̀, ẹran wọn á sì máa jẹko níbẹ̀. Ìlú náà yóò wà ní àárín rẹ̀.+
15 “Ibi tó ṣẹ́ kù jẹ́ ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) ìgbọ̀nwọ́ ní fífẹ̀, lẹ́bàá ààlà tó jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́. Ó máa jẹ́ ti gbogbo ìlú,+ wọ́n á máa gbé ibẹ̀, ẹran wọn á sì máa jẹko níbẹ̀. Ìlú náà yóò wà ní àárín rẹ̀.+