Ìsíkíẹ́lì 48:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 “Ẹgbẹ̀rún méjìdínlógún (18,000) ìgbọ̀nwọ́ ni yóò jẹ́ yí ká. Láti ọjọ́ yẹn lọ, orúkọ ìlú náà yóò máa jẹ́ Jèhófà Wà Níbẹ̀.”+
35 “Ẹgbẹ̀rún méjìdínlógún (18,000) ìgbọ̀nwọ́ ni yóò jẹ́ yí ká. Láti ọjọ́ yẹn lọ, orúkọ ìlú náà yóò máa jẹ́ Jèhófà Wà Níbẹ̀.”+