Ìsíkíẹ́lì 40:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà tó mú mi dé ibẹ̀, mo rí ọkùnrin kan tí ìrísí rẹ̀ dà bíi bàbà.+ Ó mú okùn ọ̀gbọ̀ àti ọ̀pá esùsú* tí wọ́n fi ń wọn nǹkan dání,+ ó sì dúró ní ẹnubodè. Ìfihàn 21:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹni tó ń bá mi sọ̀rọ̀ mú ọ̀pá esùsú tí a fi wúrà ṣe dání kó lè fi ṣe ìwọ̀n, láti wọn ìlú náà àti àwọn ẹnubodè rẹ̀ àti ògiri rẹ̀.+
3 Nígbà tó mú mi dé ibẹ̀, mo rí ọkùnrin kan tí ìrísí rẹ̀ dà bíi bàbà.+ Ó mú okùn ọ̀gbọ̀ àti ọ̀pá esùsú* tí wọ́n fi ń wọn nǹkan dání,+ ó sì dúró ní ẹnubodè.
15 Ẹni tó ń bá mi sọ̀rọ̀ mú ọ̀pá esùsú tí a fi wúrà ṣe dání kó lè fi ṣe ìwọ̀n, láti wọn ìlú náà àti àwọn ẹnubodè rẹ̀ àti ògiri rẹ̀.+