Ìsíkíẹ́lì 48:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ààlà tó wà ní gúúsù lẹ́gbẹ̀ẹ́ ààlà Gádì, yóò jẹ́ láti Támárì+ dé omi Mẹriba-kádéṣì,+ dé Àfonífojì,*+ títí dé Òkun Ńlá.*
28 Ààlà tó wà ní gúúsù lẹ́gbẹ̀ẹ́ ààlà Gádì, yóò jẹ́ láti Támárì+ dé omi Mẹriba-kádéṣì,+ dé Àfonífojì,*+ títí dé Òkun Ńlá.*