Ìsíkíẹ́lì 47:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “Ààlà tó wà ní gúúsù* yóò jẹ́ láti Támárì dé omi Mẹriba-kádéṣì,+ yóò dé Àfonífojì* àti Òkun Ńlá.+ Ààlà tó wà ní gúúsù* nìyí.
19 “Ààlà tó wà ní gúúsù* yóò jẹ́ láti Támárì dé omi Mẹriba-kádéṣì,+ yóò dé Àfonífojì* àti Òkun Ńlá.+ Ààlà tó wà ní gúúsù* nìyí.