Jeremáyà 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ní àkókò yẹn, wọ́n á pe Jerúsálẹ́mù ní ìtẹ́ Jèhófà;+ gbogbo orílẹ̀-èdè á kóra jọ ní orúkọ Jèhófà sí Jerúsálẹ́mù,+ wọn kò ní ya alágídí, wọn kò sì ní ṣe ohun tí ọkàn búburú wọn sọ fún wọn mọ́.” Jóẹ́lì 3:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Èmi yóò mú ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ tó ti wà lọ́rùn wọn kúrò;+Jèhófà yóò sì máa gbé ní Síónì.”+ Sekaráyà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Kígbe ayọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Síónì;+ torí mò ń bọ̀,+ èmi yóò sì máa gbé láàárín rẹ,”+ ni Jèhófà wí.
17 Ní àkókò yẹn, wọ́n á pe Jerúsálẹ́mù ní ìtẹ́ Jèhófà;+ gbogbo orílẹ̀-èdè á kóra jọ ní orúkọ Jèhófà sí Jerúsálẹ́mù,+ wọn kò ní ya alágídí, wọn kò sì ní ṣe ohun tí ọkàn búburú wọn sọ fún wọn mọ́.”