7 Màá fún wọn ní ọkàn tí á jẹ́ kí wọ́n fẹ́ láti mọ̀ mí, pé èmi ni Jèhófà.+ Wọ́n á di èèyàn mi, màá sì di Ọlọ́run wọn,+ nítorí wọ́n á fi gbogbo ọkàn wọn pa dà sọ́dọ̀ mi.+
33 “Nítorí májẹ̀mú tí màá bá ilé Ísírẹ́lì dá lẹ́yìn ìgbà yẹn nìyí,” ni Jèhófà wí. “Màá fi òfin mi sínú wọn,+ inú ọkàn wọn sì ni màá kọ ọ́ sí.+ Màá di Ọlọ́run wọn, wọ́n á sì di èèyàn mi.”+