Sáàmù 107:33, 34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ó ń sọ àwọn odò di aṣálẹ̀,Ó sì ń sọ ìṣàn omi di ilẹ̀ tó gbẹ táútáú,+ 34 Ó ń sọ ilẹ̀ eléso di aṣálẹ̀,+Nítorí ìwà burúkú àwọn tó ń gbé orí rẹ̀. Jeremáyà 6:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bí omi tútù ṣe máa ń wà nínú àmù,*Bẹ́ẹ̀ ni ìwà burúkú ṣe wà nínú ìlú yìí. Ìwà ipá àti ìparun ni ìròyìn tí à ń gbọ́ nínú rẹ̀;+Àìsàn àti àjálù ni mò ń rí níbẹ̀ nígbà gbogbo.
33 Ó ń sọ àwọn odò di aṣálẹ̀,Ó sì ń sọ ìṣàn omi di ilẹ̀ tó gbẹ táútáú,+ 34 Ó ń sọ ilẹ̀ eléso di aṣálẹ̀,+Nítorí ìwà burúkú àwọn tó ń gbé orí rẹ̀.
7 Bí omi tútù ṣe máa ń wà nínú àmù,*Bẹ́ẹ̀ ni ìwà burúkú ṣe wà nínú ìlú yìí. Ìwà ipá àti ìparun ni ìròyìn tí à ń gbọ́ nínú rẹ̀;+Àìsàn àti àjálù ni mò ń rí níbẹ̀ nígbà gbogbo.