Jeremáyà 7:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Wò ó! Ìbínú mi àti ìrunú mi yóò dà sórí ibí yìí,+ sórí èèyàn àti ẹranko, sórí igi oko àti èso ilẹ̀. Ìbínú mi yóò máa jó bí iná tí kò ṣeé pa.’+
20 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Wò ó! Ìbínú mi àti ìrunú mi yóò dà sórí ibí yìí,+ sórí èèyàn àti ẹranko, sórí igi oko àti èso ilẹ̀. Ìbínú mi yóò máa jó bí iná tí kò ṣeé pa.’+