ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 18:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ pé: “Igbe àwọn tó ń ráhùn nípa Sódómù àti Gòmórà ti pọ̀ gidigidi,+ ẹ̀ṣẹ̀ wọn sì wúwo gan-an.+

  • Àìsáyà 3:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ìrísí ojú wọn ta kò wọ́n,

      Wọ́n sì ń kéde ẹ̀ṣẹ̀ wọn bíi ti Sódómù;+

      Wọn ò fi bò rárá.

      Wọ́n* gbé, torí wọ́n ń mú àjálù wá sórí ara wọn!

  • Jeremáyà 23:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Mo ti rí àwọn ohun tó burú nínú àwọn wòlíì Jerúsálẹ́mù.

      Wọ́n ń ṣe àgbèrè,+ wọ́n sì ń rìn nínú èké;+

      Wọ́n ń ti àwọn aṣebi lẹ́yìn,*

      Wọn ò sì jáwọ́ nínú ìwà burúkú wọn.

      Lójú mi, gbogbo wọn dà bíi Sódómù,+

      Àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ sì dà bíi Gòmórà.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́