Ìsíkíẹ́lì 36:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àní màá sọ àwọn èèyàn rẹ àti ẹran ọ̀sìn rẹ di púpọ̀;+ wọ́n á bí sí i, wọ́n á sì pọ̀ sí i. Èmi yóò mú kí wọ́n máa gbé inú rẹ bíi ti tẹ́lẹ̀,+ èmi yóò sì mú kí nǹkan dáa fún yín ju ti tẹ́lẹ̀ lọ;+ ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.+
11 Àní màá sọ àwọn èèyàn rẹ àti ẹran ọ̀sìn rẹ di púpọ̀;+ wọ́n á bí sí i, wọ́n á sì pọ̀ sí i. Èmi yóò mú kí wọ́n máa gbé inú rẹ bíi ti tẹ́lẹ̀,+ èmi yóò sì mú kí nǹkan dáa fún yín ju ti tẹ́lẹ̀ lọ;+ ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.+