-
Jóòbù 35:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Ṣé ó dá ọ lójú pé o jàre tí wàá fi sọ pé,
‘Òdodo mi ju ti Ọlọ́run lọ’?+
-
-
Òwe 19:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ìwà òmùgọ̀ èèyàn ló ń lọ́ ọ̀nà rẹ̀ po,
Tí ọkàn rẹ̀ fi ń bínú gidigidi sí Jèhófà.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 33:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 “Àmọ́ àwọn èèyàn rẹ sọ pé, ‘Ọ̀nà Jèhófà kò tọ́,’ nígbà tó jẹ́ pé ọ̀nà tiwọn ni kò tọ́.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 33:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 “Àmọ́ ẹ ti sọ pé, ‘Ọ̀nà Jèhófà kò tọ́.’+ Èmi yóò fi ìwà kálukú dá a lẹ́jọ́, ìwọ ilé Ísírẹ́lì.”
-