Àìsáyà 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bí ẹ ṣe ń wá síwájú mi,+Tí ẹ̀ ń tẹ àgbàlá mi mọ́lẹ̀,Ta ló ní kí ẹ ṣe bẹ́ẹ̀?+ Àìsáyà 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Tí ẹ bá sì tẹ́ ọwọ́ yín,Mò ń fojú mi pa mọ́ fún yín.+ Bí ẹ tiẹ̀ ń gbàdúrà púpọ̀,+Mi ò gbọ́ àdúrà yín;+Ẹ̀jẹ̀ kún ọwọ́ yín.+ Ìsíkíẹ́lì 14:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Ọmọ èèyàn, àwọn ọkùnrin yìí ti pinnu láti máa tẹ̀ lé àwọn òrìṣà ẹ̀gbin* wọn, wọ́n sì ti ṣe ohun ìkọ̀sẹ̀ tó ń mú kí àwọn èèyàn dẹ́ṣẹ̀. Ṣé kí n jẹ́ kí wọ́n wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ mi?+
15 Tí ẹ bá sì tẹ́ ọwọ́ yín,Mò ń fojú mi pa mọ́ fún yín.+ Bí ẹ tiẹ̀ ń gbàdúrà púpọ̀,+Mi ò gbọ́ àdúrà yín;+Ẹ̀jẹ̀ kún ọwọ́ yín.+
3 “Ọmọ èèyàn, àwọn ọkùnrin yìí ti pinnu láti máa tẹ̀ lé àwọn òrìṣà ẹ̀gbin* wọn, wọ́n sì ti ṣe ohun ìkọ̀sẹ̀ tó ń mú kí àwọn èèyàn dẹ́ṣẹ̀. Ṣé kí n jẹ́ kí wọ́n wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ mi?+