Sáàmù 81:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí náà, mo jẹ́ kí wọ́n máa ṣe ohun tí agídí ọkàn wọn sọ;Wọ́n ń ṣe ohun tí wọ́n rò pé ó tọ́.*+