Àìsáyà 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ má ṣe mú àwọn ọrẹ ọkà tí kò ní láárí wá mọ́. Tùràrí yín ń rí mi lára.+ Àwọn òṣùpá tuntun,+ sábáàtì+ àti pípe àpéjọ,+Mi ò lè fara da bí ẹ ṣe ń pidán,+ tí ẹ sì tún ń ṣe àpéjọ ọlọ́wọ̀. Ìsíkíẹ́lì 23:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Lẹ́yìn tí wọ́n pa àwọn ọmọ wọn, tí wọ́n sì fi wọ́n rúbọ sí àwọn òrìṣà ẹ̀gbin wọn,+ wọ́n wá sínú ibi mímọ́ mi kí wọ́n lè sọ ọ́ di aláìmọ́+ ní ọjọ́ yẹn gan-an. Ohun tí wọ́n ṣe nínú ilé mi nìyẹn.
13 Ẹ má ṣe mú àwọn ọrẹ ọkà tí kò ní láárí wá mọ́. Tùràrí yín ń rí mi lára.+ Àwọn òṣùpá tuntun,+ sábáàtì+ àti pípe àpéjọ,+Mi ò lè fara da bí ẹ ṣe ń pidán,+ tí ẹ sì tún ń ṣe àpéjọ ọlọ́wọ̀.
39 Lẹ́yìn tí wọ́n pa àwọn ọmọ wọn, tí wọ́n sì fi wọ́n rúbọ sí àwọn òrìṣà ẹ̀gbin wọn,+ wọ́n wá sínú ibi mímọ́ mi kí wọ́n lè sọ ọ́ di aláìmọ́+ ní ọjọ́ yẹn gan-an. Ohun tí wọ́n ṣe nínú ilé mi nìyẹn.