ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 26:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 Wọ́n á wá jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ ara wọn+ àti ẹ̀ṣẹ̀ àwọn bàbá wọn pẹ̀lú ìwà àìṣòótọ́ àwọn bàbá wọn, wọ́n á sì gbà pé àwọn ti hùwà àìṣòótọ́ torí wọ́n kẹ̀yìn sí mi.+

  • Ìsíkíẹ́lì 6:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àwọn tó bá yè bọ́ yóò rántí mi láàárín àwọn orílẹ̀-èdè tó kó wọn lẹ́rú.+ Wọ́n á rí i pé ó dùn mí gan-an bí ọkàn àìṣòótọ́* wọn ṣe mú kí wọ́n kẹ̀yìn sí mi+ àti bí ojú wọn ṣe mú kí ọkàn wọn fà sí àwọn òrìṣà ẹ̀gbin wọn.*+ Gbogbo iṣẹ́ ibi àtàwọn ohun ìríra tí wọ́n ti ṣe yóò kó ìtìjú bá wọn, wọ́n á sì kórìíra rẹ̀ gidigidi.+

  • Ìsíkíẹ́lì 16:61
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 61 Ìwọ yóò rántí ìwà rẹ, ojú á sì tì ọ́+ nígbà tí o bá gba àwọn arábìnrin rẹ, àwọn ẹ̀gbọ́n àti àwọn àbúrò rẹ, èmi yóò sì fi wọ́n fún ọ bí ọmọbìnrin, àmọ́ kì í ṣe torí májẹ̀mú rẹ.’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́