Ìsíkíẹ́lì 12:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 ‘“Torí èmi Jèhófà, yóò sọ̀rọ̀. Ohun tí mo bá sọ sì máa ṣẹ láìjáfara.+ Ìwọ ọlọ̀tẹ̀ ilé, ní àwọn ọjọ́ rẹ,+ ni èmi yóò sọ ọ̀rọ̀ náà, màá sì mú un ṣẹ,” ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.’”
25 ‘“Torí èmi Jèhófà, yóò sọ̀rọ̀. Ohun tí mo bá sọ sì máa ṣẹ láìjáfara.+ Ìwọ ọlọ̀tẹ̀ ilé, ní àwọn ọjọ́ rẹ,+ ni èmi yóò sọ ọ̀rọ̀ náà, màá sì mú un ṣẹ,” ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.’”