-
Jeremáyà 16:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “Nítorí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Wò ó ní ibí yìí, lójú rẹ àti ní ìgbà ayé rẹ, màá fòpin sí ìró ayọ̀ àti ìdùnnú, ohùn ọkọ ìyàwó àti ohùn ìyàwó.’+
-