Jeremáyà 13:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ìwà àgbèrè rẹ + àti bí o ṣe ń yán bí ẹṣin tó fẹ́ gùn,Ìṣekúṣe rẹ tó ń ríni lára.* Lórí àwọn òkè àti ní pápá,Mo ti rí ìwà ẹ̀gbin rẹ.+ O gbé, ìwọ Jerúsálẹ́mù! Títí dìgbà wo lo fi máa jẹ́ aláìmọ́?”+
27 Ìwà àgbèrè rẹ + àti bí o ṣe ń yán bí ẹṣin tó fẹ́ gùn,Ìṣekúṣe rẹ tó ń ríni lára.* Lórí àwọn òkè àti ní pápá,Mo ti rí ìwà ẹ̀gbin rẹ.+ O gbé, ìwọ Jerúsálẹ́mù! Títí dìgbà wo lo fi máa jẹ́ aláìmọ́?”+