Jóṣúà 24:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Torí náà, ẹ bẹ̀rù Jèhófà, kí ẹ sì máa fi ìwà títọ́* àti òótọ́ inú* sìn ín,+ kí ẹ mú àwọn ọlọ́run tí àwọn baba ńlá yín sìn ní òdìkejì Odò* àti ní Íjíbítì kúrò,+ kí ẹ sì máa sin Jèhófà.
14 “Torí náà, ẹ bẹ̀rù Jèhófà, kí ẹ sì máa fi ìwà títọ́* àti òótọ́ inú* sìn ín,+ kí ẹ mú àwọn ọlọ́run tí àwọn baba ńlá yín sìn ní òdìkejì Odò* àti ní Íjíbítì kúrò,+ kí ẹ sì máa sin Jèhófà.