-
Ìsíkíẹ́lì 24:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Àárọ̀ ni mo bá àwọn èèyàn náà sọ̀rọ̀, ìyàwó mi sì kú ní alẹ́. Torí náà, nígbà tí ilẹ̀ mọ́, mo ṣe ohun tí Ọlọ́run pa láṣẹ fún mi.
-