ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 74:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Wọ́n sọ iná sí ibi mímọ́ rẹ.+

      Wọ́n sọ àgọ́ ìjọsìn tí o fi orúkọ rẹ pè di aláìmọ́, wọ́n sì wó o lulẹ̀.

  • Sáàmù 79:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 79 Ọlọ́run, àwọn orílẹ̀-èdè ti ya wọnú ogún rẹ;+

      Wọ́n ti sọ tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ di ẹlẹ́gbin;+

      Wọ́n ti sọ Jerúsálẹ́mù di àwókù.+

  • Jeremáyà 7:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Bí mo ti ṣe sí Ṣílò, bẹ́ẹ̀ ni màá ṣe sí ilé tí a fi orúkọ mi pè,+ èyí tí ẹ gbẹ́kẹ̀ lé+ àti sí ibi tí mo fún ẹ̀yin àti àwọn baba ńlá yín.+

  • Ìdárò 1:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Elénìní ti kó gbogbo ìṣúra rẹ̀.+

      Nítorí ìṣojú rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè wá sínú ibi mímọ́ rẹ̀,+

      Àwọn tí o pàṣẹ pé kí wọ́n má ṣe wá sínú ìjọ rẹ.

  • Ìdárò 2:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Jèhófà ti pa pẹpẹ rẹ̀ tì;

      Ó ti ta ibi mímọ́ rẹ̀ nù.+

      Ó ti fi ògiri àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò lé ọ̀tá lọ́wọ́.+

      Wọ́n ti gbé ohùn wọn sókè ní ilé Jèhófà,+ bíi ti ọjọ́ àjọyọ̀.

  • Ìsíkíẹ́lì 9:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Lẹ́yìn náà, ó sọ fún wọn pé: “Ẹ sọ ilé náà di ẹlẹ́gbin, kí ẹ sì fi òkú èèyàn kún inú àwọn àgbàlá.+ Ẹ lọ!” Ni wọ́n bá lọ, wọ́n sì pa àwọn èèyàn ní ìlú náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́