-
Jeremáyà 49:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Sí Édómù, ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí:
“Ṣé kò sí ọgbọ́n mọ́ ní Témánì ni?+
Ṣé kò sí ìmọ̀ràn rere mọ́ lọ́dọ̀ àwọn olóye ni?
Ṣé ọgbọ́n wọn ti jẹrà ni?
8 Ẹ sá pa dà!
Ẹ lọ máa gbé ní àwọn ibi tó jin kòtò, ẹ̀yin tó ń gbé ní Dédánì!+
Nítorí màá mú àjálù bá Ísọ̀
Nígbà tí àkókò tí màá yí ojú mi sí i bá tó.
-