Àìsáyà 11:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Wọ́n máa já ṣòòrò wálẹ̀ sí gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́* àwọn Filísínì lápá ìwọ̀ oòrùn;Wọ́n jọ máa kó ẹrù àwọn ará Ìlà Oòrùn. Wọ́n máa na ọwọ́ wọn sí* Édómù+ àti Móábù,+Àwọn ọmọ Ámónì sì máa di ọmọ abẹ́ wọn.+ Àìsáyà 63:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 63 Ta ló ń bọ̀ láti Édómù+ yìí,Tó ń bọ̀ láti Bósírà,+ tó wọ aṣọ tí àwọ̀ rẹ̀ ń tàn yòò,*Tó wọ aṣọ tó dáa gan-an,Tó ń yan bọ̀ nínú agbára ńlá rẹ̀? “Èmi ni, Ẹni tó ń fi òdodo sọ̀rọ̀,Ẹni tó lágbára gan-an láti gbani là.”
14 Wọ́n máa já ṣòòrò wálẹ̀ sí gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́* àwọn Filísínì lápá ìwọ̀ oòrùn;Wọ́n jọ máa kó ẹrù àwọn ará Ìlà Oòrùn. Wọ́n máa na ọwọ́ wọn sí* Édómù+ àti Móábù,+Àwọn ọmọ Ámónì sì máa di ọmọ abẹ́ wọn.+
63 Ta ló ń bọ̀ láti Édómù+ yìí,Tó ń bọ̀ láti Bósírà,+ tó wọ aṣọ tí àwọ̀ rẹ̀ ń tàn yòò,*Tó wọ aṣọ tó dáa gan-an,Tó ń yan bọ̀ nínú agbára ńlá rẹ̀? “Èmi ni, Ẹni tó ń fi òdodo sọ̀rọ̀,Ẹni tó lágbára gan-an láti gbani là.”