Jeremáyà 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Gé igi lulẹ̀, kí o sì mọ òkìtì láti dó ti Jerúsálẹ́mù.+ Ìlú tí ó gbọ́dọ̀ jíhìn ni;Ìnilára nìkan ló wà nínú rẹ̀.+ Jeremáyà 32:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Wò ó! Àwọn èèyàn ti wá mọ òkìtì láti dó ti ìlú náà kí wọ́n lè gbà á,+ ó sì dájú pé idà+ àti ìyàn pẹ̀lú àjàkálẹ̀ àrùn*+ yóò mú kí ìlú náà ṣubú sọ́wọ́ àwọn ará Kálídíà tó ń bá a jà; gbogbo ohun tí o sọ ló ti ṣẹ bí ìwọ náà ṣe rí i báyìí.
6 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Gé igi lulẹ̀, kí o sì mọ òkìtì láti dó ti Jerúsálẹ́mù.+ Ìlú tí ó gbọ́dọ̀ jíhìn ni;Ìnilára nìkan ló wà nínú rẹ̀.+
24 Wò ó! Àwọn èèyàn ti wá mọ òkìtì láti dó ti ìlú náà kí wọ́n lè gbà á,+ ó sì dájú pé idà+ àti ìyàn pẹ̀lú àjàkálẹ̀ àrùn*+ yóò mú kí ìlú náà ṣubú sọ́wọ́ àwọn ará Kálídíà tó ń bá a jà; gbogbo ohun tí o sọ ló ti ṣẹ bí ìwọ náà ṣe rí i báyìí.