Jeremáyà 14:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Tí wọ́n bá gbààwẹ̀, mi ò ní fetí sí ẹ̀bẹ̀ wọn,+ tí wọ́n bá sì fi odindi ẹbọ sísun àti ọrẹ ọkà rúbọ, inú mi ò ní dùn sí wọn,+ nítorí pé idà àti ìyàn àti àjàkálẹ̀ àrùn* ni màá fi pa wọ́n.”+ Jeremáyà 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bí wọ́n bá sì bi ọ́ pé, ‘Kí ló máa ṣẹlẹ̀ sí wa?’ kí o sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Àjàkálẹ̀ àrùn máa pa àwọn kan lára yín! Idà máa pa àwọn kan lára yín!+ Ìyàn máa pa àwọn míì lára yín! Àwọn kan lára yín sì máa lọ sóko ẹrú!”’+
12 Tí wọ́n bá gbààwẹ̀, mi ò ní fetí sí ẹ̀bẹ̀ wọn,+ tí wọ́n bá sì fi odindi ẹbọ sísun àti ọrẹ ọkà rúbọ, inú mi ò ní dùn sí wọn,+ nítorí pé idà àti ìyàn àti àjàkálẹ̀ àrùn* ni màá fi pa wọ́n.”+
2 Bí wọ́n bá sì bi ọ́ pé, ‘Kí ló máa ṣẹlẹ̀ sí wa?’ kí o sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Àjàkálẹ̀ àrùn máa pa àwọn kan lára yín! Idà máa pa àwọn kan lára yín!+ Ìyàn máa pa àwọn míì lára yín! Àwọn kan lára yín sì máa lọ sóko ẹrú!”’+