Ìsíkíẹ́lì 28:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 O bẹ̀rẹ̀ sí í gbéra ga nínú ọkàn rẹ torí ẹwà rẹ.+ Ògo rẹ tó rẹwà mú kí o ba ọgbọ́n rẹ jẹ́.+ Èmi yóò jù ọ́ sí ilẹ̀.+ Màá sì mú kí àwọn ọba fi ọ́ ṣe ìran wò.
17 O bẹ̀rẹ̀ sí í gbéra ga nínú ọkàn rẹ torí ẹwà rẹ.+ Ògo rẹ tó rẹwà mú kí o ba ọgbọ́n rẹ jẹ́.+ Èmi yóò jù ọ́ sí ilẹ̀.+ Màá sì mú kí àwọn ọba fi ọ́ ṣe ìran wò.