Jẹ́nẹ́sísì 10:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mísíráímù bí Lúdímù,+ Ánámímù, Léhábímù, Náfítúhímù,+ 14 Pátírúsímù,+ Kásílúhímù (ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn Filísínì+ ti wá) àti Káfítórímù.+ Ìsíkíẹ́lì 30:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá pa Pátírọ́sì+ run, màá dá iná sí Sóánì, màá sì dá Nóò* lẹ́jọ́.+
13 Mísíráímù bí Lúdímù,+ Ánámímù, Léhábímù, Náfítúhímù,+ 14 Pátírúsímù,+ Kásílúhímù (ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn Filísínì+ ti wá) àti Káfítórímù.+