Jẹ́nẹ́sísì 10:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mísíráímù bí Lúdímù,+ Ánámímù, Léhábímù, Náfítúhímù,+ 14 Pátírúsímù,+ Kásílúhímù (ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn Filísínì+ ti wá) àti Káfítórímù.+ Jeremáyà 44:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà gbọ́ nípa gbogbo Júù tó ń gbé ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ ìyẹn àwọn tó ń gbé ní Mígídólì,+ ní Tápánẹ́sì,+ ní Nófì*+ àti ní ilẹ̀ Pátírọ́sì,+ pé:
13 Mísíráímù bí Lúdímù,+ Ánámímù, Léhábímù, Náfítúhímù,+ 14 Pátírúsímù,+ Kásílúhímù (ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn Filísínì+ ti wá) àti Káfítórímù.+
44 Ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà gbọ́ nípa gbogbo Júù tó ń gbé ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ ìyẹn àwọn tó ń gbé ní Mígídólì,+ ní Tápánẹ́sì,+ ní Nófì*+ àti ní ilẹ̀ Pátírọ́sì,+ pé: