-
Ìsíkíẹ́lì 32:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Èmi yóò pa ọ́ tì sórí ilẹ̀;
Màá jù ọ́ sórí pápá gbalasa.
Màá mú kí gbogbo ẹyẹ ojú ọ̀run bà lé ọ,
Màá sì fi ọ́ bọ́ àwọn ẹran inú igbó ní gbogbo ayé.+
-