16 Tí ìró ìṣubú rẹ̀ bá dún, màá mú kí àwọn orílẹ̀-èdè gbọ̀n rìrì nígbà tí mo bá mú un lọ sí Isà Òkú pẹ̀lú gbogbo àwọn tó ń lọ sínú kòtò àti gbogbo igi Édẹ́nì,+ èyí tó dáa jù tó sì jẹ́ ààyò ti Lẹ́bánónì, gbogbo àwọn tó ń rí omi mu dáadáa, yóò rí ìtùnú ní ilẹ̀ tó wà nísàlẹ̀.