ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 55:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+

      Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;

      Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+

      Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+

  • Ìsíkíẹ́lì 18:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 “‘Àmọ́, bí ẹni burúkú bá yí pa dà kúrò nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tó ti dá, tó ń pa àwọn àṣẹ mi mọ́, tó ń ṣe ohun tó tọ́ àti ohun tó jẹ́ òdodo, ó dájú pé yóò máa wà láàyè. Kò ní kú.+

  • Míkà 6:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ó ti sọ ohun tó dára fún ọ, ìwọ ọmọ aráyé.

      Kí sì ni Jèhófà fẹ́ kí o ṣe?*

      Bí kò ṣe pé kí o ṣe ìdájọ́ òdodo,*+ kí o mọyì jíjẹ́ adúróṣinṣin,*+

      Kí o sì mọ̀wọ̀n ara rẹ+ bí o ṣe ń bá Ọlọ́run rẹ rìn!+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́